Job 16:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn ọdún díẹ̀ sí i, n óo lọ àjò àrèmabọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori nigbati iye ọdun diẹ rekọja tan, nigbana ni emi o lọ si ibi ti emi kì yio pada bọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí nígbà tí iye ọdun díẹ̀ rékọjá tán, nígbà náà ni èmi ó lọ sí ibi tí èmi kì yóò padà bọ̀.