Job 16:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dájúdájú Ọlọrun ti dá mi lágara, ó ti sọ gbogbo ilé mi di ahoro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nisisiyi, o da mi lagara, iwọ (Ọlọrun) mu gbogbo ẹgbẹ mi takete.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ó dá mi lágara; Ìwọ (Ọlọ́run) mú gbogbo ẹgbẹ́ mi takété.