Job 17:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ní tiyín, bí ẹ tilẹ̀ ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ, n kò ní ka ẹnikẹ́ni kún ọlọ́gbọ́n láàrin yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi o ṣe ti gbogbo nyin, ẹ yipada, ki ẹ si tun bọ̀ nisisiyi, emi kò le ri ọlọgbón kan ninu nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti gbogbo yín, ẹ yí padà, kí ẹ sì tún bọ̀ nísinsin yìí; èmi kò le rí ọlọgbọ́n kan nínú yín.