Job 17:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Níwọ̀n ìgbà tí o ti mú ọkàn wọn yigbì sí ìmọ̀, nítorí náà, o kò ní jẹ́ kí wọ́n borí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe iwọ ti sé wọn laiya kuro ninu oye, nitorina iwọ kì yio gbé wọn leke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé ìwọ ti ṣé wọ́n láyà kúrò nínú òyè; nítorí náà ìwọ kì yóò gbé wọn lékè.