Job 17:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ẹnìkan bá hùwà ọ̀dàlẹ̀, tí ó ṣòfófó àwọn ọ̀rẹ́, kí ó lè pín ninu ohun ìní wọn, àwọn ọmọ olúwarẹ̀ yóo jìyà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o fi awọn ọrẹ hàn fun igára, on ni oju awọn ọmọ rẹ̀ yio mu ofo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó fi àwọn ọ̀rẹ́ hàn fún ìgárá, òun ni ojú àwọn ọmọ rẹ̀ yóò mú òfo.