Job 18:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò lọ́mọ, kò lọ́mọ ọmọ, kò sì sí ẹni tí yóo rọ́pò rẹ̀ ní ibùgbé rẹ̀, láàrin àwọn eniyan rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kì yio ni ọmọ bibikunrin tabi ajọbi-kunrin ninu awọn enia rẹ̀, bẹ̃ni kò si ẹnikan ti o kù ninu agbo ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kì yóò ní ọmọ tàbí ọmọ ọmọ nínu àwọn ènìyàn rẹ̀, Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹnikẹ́ni tí yóò kù nínú agbo ilé rẹ̀.