Job 18:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìwọ tí o faraya nítorí inú ń bí ọ, ṣé kí á sá kúrò láyé nítorí rẹ ni, tabi kí á ṣí àwọn àpáta nípò pada?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ nfa ara rẹ ya pẹrẹpẹrẹ ninu ibinu rẹ, ki a ha kọ̀ aiye silẹ nitori rẹ bi? tabi ki a ṣi apata kuro ni ipo rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ fa ara rẹ ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ nínú ìbínú rẹ̀; kí a ha kọ ayé sílẹ̀ nítorí rẹ̀ bi? Tàbí kí a sí àpáta kúrò ní ipò rẹ̀?