Job 19:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ẹ bá wí pé, ‘Báwo ni a óo ṣe lépa rẹ̀!’ Nítorí pé òun ló jẹ̀bi ọ̀rọ̀ yìí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi ẹnyin ba wipe, Awa o ti lepa rẹ̀ to! ati pe, gbongbo ọ̀rọ na li a sa ri li ọwọ mi,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Bí ẹ̀yin bá wí pé, ‘àwa ó ti lépa rẹ̀ tó! Àti pé, gbogbo ọ̀rọ̀ náà ni a ṣáà rí ní ọwọ́ rẹ̀,’