Job 20:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu ọlá ńlá rẹ̀ yóo wà ninu àhámọ́, ìbànújẹ́ yóo máa fi tagbára-tagbára bá a jà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu titó ìkún rẹ̀ yio wà ninu ihale, ọwọ gbogbo awọn oniyọnu ni yio dide si i lori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú ànító rẹ̀, ìdààmú yóò dé bá a; àwọn ènìyàn búburú yóò dáwọ́ jọ lé e lórí.