Job 21:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ń sọ fún Ọlọrun pé, ‘Fi wá sílẹ̀! A kò fẹ́ mọ òfin rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni nwọn ṣe wi fun Ọlọrun pe, Lọ kuro lọdọ wa, nitoripe awa kò fẹ ìmọ ipa ọ̀na rẹ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí fún Ọlọ́run pé, lọ kúrò lọ́dọ̀ wa, nítorí pé wọn kò fẹ́ ìmọ̀ ipa ọ̀nà rẹ!