Job 21:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“O ní, ‘Ọlọrun ń to àìdára wọn jọ de àwọn ọmọ wọn.’ Jẹ́ kí ó dà á lé wọn lórí, kí wọ́n baà lè mọ ohun tí wọ́n ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun to ìya-ẹ̀ṣẹ rẹ̀ jọ fun awọn ọmọ rẹ̀, o san a fun u, yio si mọ̀ ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin wí pé, ‘Ọlọ́run to iya ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jọ fún àwọn ọmọ rẹ̀.’ Jẹ́ kí ó san án fún un, yóò sì mọ̀ ọ́n.