Job 21:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣé ẹnìkan lè kọ́ Ọlọrun ní ìmọ̀, nígbà tí ó jẹ́ pé òun ni onídàájọ́ àwọn tí wọ́n wà ní ibi gíga?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnikẹni le ikọ́ Ọlọrun ni ìmọ? on ni sa nṣe idajọ ẹni ibi giga.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹnikẹ́ni le íkọ́ Ọlọ́run ní ìmọ̀? Òun ní í sáa ń ṣe ìdájọ́ ẹni ibi gíga.