Job 21:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bákan náà ni gbogbo wọn ṣe sùn ninu erùpẹ̀, tí ìdin sì bò wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o dubulẹ bakanna ninu erupẹ, kòkoro yio si ṣùbo wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n o dùbúlẹ̀ bákan náà nínú erùpẹ̀, kòkòrò yóò sì ṣùbò wọ́n.