Job 21:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ẹ wí pé, ‘Níbo ni ilé àwọn eniyan ńlá wà; níbo sì ni àgọ́ àwọn aṣebi wà?’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti ẹnyin wipe, nibo ni ile awọn ọmọ alade, ati nibo ni agọ awọn enia buburu nì gbe wà?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ẹ̀yin wí pé, ‘Níbo ní ilé ọmọ aládé, àti níbo ní àgọ́ àwọn ènìyàn búburú nì gbé wà?’