Job 21:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, kí ni ìsọkúsọ tí ẹ lè fi tù mí ninu? Kò sóhun tó kù ninu ọ̀rọ̀ yín, tó ju irọ́ lọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
E ha ti ṣe ti ẹnyin fi ntù mi ninu lasan! bi o ṣepe ni idahùn nyin eké kù nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èé ha ti ṣe tí ẹ̀yin fi ń tù mí nínú lásán, bí ò ṣepé ní ìdáhùn yín, eké kù níbẹ̀!”