Job 22:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
wọ́n ń wí pé, ‘Dájúdájú, àwọn ọ̀tá wa ti parun, iná sì ti jó gbogbo ohun tí wọ́n fi sílẹ̀.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lotitọ awọn ọta wa ni a ke kuro, iná yio si jó iyokù wọn run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lótìítọ́ àwọn ọ̀ta wa ni a ké kúrò, iná yóò sì jó oró wọn run.