Job 22:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nígbà náà ni o óo láyọ̀ ninu Olodumare, o óo sì lè dúró níwájú Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lotitọ nigbana ni iwọ o ni inu didùn ninu Olodumare, iwọ o si gbe oju rẹ soke sọdọ Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lótìítọ́ nígbà náà ní ìwọ ó ní inú dídùn nínú Olódùmáarè, ìwọ ó sì gbé ojú rẹ sókè sọ́dọ̀ Ọlọ́run.