Job 24:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Kí ló dé tí Olodumare kò fi yan ọjọ́ ìdájọ́, kí àwọn tí wọ́n mọ̀ ọ́n sì rí ọjọ́ náà?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ẼṢE bi igba-igba kò pamọ lọdọ Olodumare; ti awọn ojulumọ rẹ̀ kò ri ọjọ rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Se bí ìgbà kò pamọ́ lọ́dọ̀ Olódùmárè fún ìdájọ́, èéṣe tí ojúlùmọ̀ rẹ̀ kò fi rí ọjọ́ rẹ̀?