Job 24:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọn ń kú lọ ń kérora ní ìgboro, àwọn tí a pa lára ń ké fún ìrànlọ́wọ́, ṣugbọn Ọlọrun kò fetísí adura wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia nkerora lati ilu wá, ọkàn awọn ẹniti o gbọgbẹ kigbe soke; sibẹ Ọlọrun kò kiyesi iwère na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn ń kérora láti ìlú wá, ọkàn àwọn ẹni tí ó gbọgbẹ́ kígbe sókè; fún ìrànlọ́wọ́ ṣíbẹ̀ Ọlọ́run kò kíyèsí àṣìṣe náà.