Job 24:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Sibẹsibẹ Ọlọrun fi ẹ̀mí gígùn fún alágbára nípa agbára rẹ̀; wọn á gbéra nígbà tí ayé bá sú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O fi ipá rẹ̀ fà alagbara lọ pẹlu; o dide, kò si ẹniti ẹmi rẹ̀ da loju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó fi ipá Ọlọ́run rẹ̀ fà alágbára lọ pẹ̀lú; Ó dìde, kò sí ẹni tí ẹ̀mí rẹ̀ dá lójú.