Job 24:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn a máa sùn ní ìhòòhò ní gbogbo òru, wọn kìí sìí rí aṣọ fi bora nígbà òtútù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nihoho ni nwọn ma sùn laini aṣọ, ti nwọn kò ni ibora ninu otutu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní hòòhò ni wọn má a sùn láìní aṣọ, tí wọn kò ní ìbora nínú òtútù.