Job 26:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn òpó ọ̀run mì tìtì, wọ́n sì wárìrì nítorí ìbáwí rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọwọn òpo ọrun wáriri, ẹnu si yà wọn si ibawi rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀wọ̀n òpó ọ̀run wárìrì, ẹnu sì yà wọ́n sì ìbàwí rẹ̀.