Job 27:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ìpín ẹni ibi láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun nìyí, òun ni ogún tí àwọn aninilára ń rí gbà lọ́dọ̀ Olodumare:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi ni ipín enia buburu lọdọ Ọlọrun, ati ogún awọn aninilara, ti nwọn o gbà lọwọ Olodumare.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ̀yin ni ìpín ènìyàn búburú lọ́dọ̀ Ọlọ́run, àti ogún àwọn aninilára, tí wọ́n ó gbà lọ́wọ́ Olódùmáre: