Job 27:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí àwọn ọmọ rẹ̀ bá ń pọ̀ sí i, kí ogun baà lè pa wọ́n ni, oúnjẹ kò sì ní ká wọn lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi awọn ọmọ rẹ̀ ba di pupọ̀, fun idà ni, awọn ọmọ-ọmọ rẹ̀ kì yio yo fun onjẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí àwọn ọmọ rẹ bá di púpọ̀, fún idà ni; àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ kì yóò yó fún oúnjẹ.