Job 27:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ tí wọn bá gbẹ̀yìn rẹ̀, àjàkálẹ̀ àrùn ni yóo pa wọ́n, àwọn opó wọn kò sì ní ṣọ̀fọ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o kù ninu tirẹ̀ li a o sinkú ninu ajakalẹ àrun: awọn opó rẹ̀ kì yio si sọkún.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó kú nínú tirẹ̀ ni a ó sìnkú nínú àjàkálẹ̀-àrùn: àwọn opó rẹ̀ kì yóò sì sunkún fún wọn.