Job 28:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn á gbẹ́ kòtò ninu àfonífojì, níbi tí ó jìnnà sí ibi tí eniyan ń gbé, àwọn arìnrìnàjò á gbàgbé wọn, wọn á takété sí àwọn eniyan, wọn á sì máa rọ̀ dirodiro sọ́tùn-ún sósì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn wá iho ilẹ ti o jìn si awọn ti o ngbe oke, awọn ti ẹsẹ enia gbagbe nwọn rọ si isalẹ, nwọn rọ si isalẹ jina si awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n wa ihò ilẹ̀ tí ó jìn sí àwọn tí ń gbé òkè, àwọn tí ẹṣẹ̀ ènìyàn gbàgbé; wọ́n rọ́ sí ìsàlẹ̀, wọ́n rọ́ sí ìsàlẹ̀ jìnnà sí àwọn ènìyàn.