Job 28:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ẹranko onigbeeraga kò tíì tẹ ojú ọ̀nà náà, kinniun kò sì tíì gba ibẹ̀ kọjá rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ kiniun kò rin ibẹ rí, bẹ̃ni kiniun ti nké ramuramu kò kọja nibẹ rí.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹrankan agbéraga kò rìn ibẹ̀ rí, bẹ́ẹ̀ ni kìnnìún tí ń ké ramúramù kò kọjá níbẹ̀ rí.