Job 29:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn olórí á panumọ́, ahọ́n wọn á lẹ̀ mọ́ wọn lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọlọla dakẹ, ahọn wọn si lẹmọ èrigi ẹnu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ ọlọ́lá dákẹ́, ahọ́n wọn sì lẹ̀mọ́ èrìgì ẹnu wọn.