Job 29:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n gbọ́ nípa mi, ń pè mí ní ẹni ibukun, àwọn tí wọ́n rí mi ń kan sáárá sí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe eti gbọ́ ti emi, a si sure fun mi, oju si ri mi, on a jẹri mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí etí gbọ́, ó sì súre fún mi, àti nígbà tí ojú sì rí mi, ó jẹ́rìí mi;