Job 29:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé mò ń ran àwọn aláìní tí ń ké lọ́wọ́, ati àwọn aláìníbaba tí wọn kò ní olùrànlọ́wọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti mo gba talaka ti nsọkun, ati alainibaba, ati alaini oluranlọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí mo gbà talákà tí n fẹ́ ìrànlọ́wọ́, àti aláìní baba, tí kò sí olùrànlọ́wọ́ fún un