Job 29:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nígbà náà, mo rò pé, n óo gbòó, n óo tọ̀ọ́ láyé, ati pé inú ilé mi ni n óo sì kú sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni mo wipe, emi o kú ninu itẹ mi, emi o si mu ọjọ mi pọ̀ si i bi iyanrin. (bi ọjọ ti ẹiyẹ Feniksi.)
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà náà ni mo rò pé, ‘Èmi yóò kú nínú ilé mi, èmi yóò sì mú ọjọ́ mi pọ̀ sí i bí i yanrìn.