Job 29:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo jókòó bí ọba, mò ń tọ́ wọn sọ́nà, mo dàbí ọba láàrin àwọn ọmọ ogun rẹ̀, bí olùtùnú fún oníròbìnújẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo la ọ̀na silẹ fun wọn, mo si joko bi Olu, mo si joko bi ọba ninu ogun, bi ẹniti ntù aṣọ̀fọ̀ ninu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo la ọ̀nà sílẹ̀ fún wọn, mo sì jókòó bí olóyè wọn; mo jókòó bí ọba ní àárin ológun rẹ̀; mo sì rí bí ẹni tí ń tu ẹni tí ń sọ̀fọ̀ nínú.