Job 3:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Kí ló dé tí n kò kú nígbà tí ìyá mi ń rọbí lọ́wọ́, tí ó fẹ́ bí mi, tabi kí n kú, lẹsẹkẹsẹ tí wọ́n bí mi?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẽṣe ti emi kò fi kú lati inu wá, tabi ti emi kò fi pin ẹmi nigbati mo ti inu jade wá?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èéṣe tí èmi kò fi kú láti inú wá, tàbí tí èmi kò fi pín ẹ̀mí ní ìgbà tí mo ti inú jáde wá?