Job 3:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
pẹlu àwọn ọba ati àwọn ìgbìmọ̀ àgbáyé, tí wọ́n ti sùn, àwọn tí wọ́n tún àlàpà kọ́ fún ara wọn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlu awọn ọba ati igbimọ aiye, ti o mọle takete fun ara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
pẹ̀lú àwọn ọba àti ìgbìmọ̀ ayé tí ìmọ́lẹ̀ takété fún ara wọn.