Job 3:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tabi pẹlu àwọn ọmọ aládé tí wọ́n ní wúrà, tí fadaka sì kún ilé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tabi pẹlu awọn ọmọ-alade ti o ni wura, ti nwọn si fi fadakà kún inu ile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tàbí pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládé tí ó ní wúrà, tí wọ́n sì fi fàdákà kun ilé wọn