Job 3:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Níbi tí àwọn oníṣẹ́ ibi kò ti lágbára mọ́, tí àwọn tí gbogbo nǹkan ti sú gbé ń sinmi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nibẹ ni ẹni-buburu ṣiwọ iyọnilẹnu, nibẹ ẹni-ãrẹ̀ wà ninu isimi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ni ẹni-búburú síwọ́ ìyọ nilẹ́nu, níbẹ̀ ni ẹni àárẹ̀ wà nínú ìsinmi.