Job 3:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí inú wọn ìbá dùn lọpọlọpọ bí wọ́n bá rí ẹni gbé wọn sin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o yọ̀ gidigidi, ti inu wọn si dùn nigbati nwọn ba le wá isa-okú ri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó yọ̀ gidigidi, tí inú wọ́n sì dùn nígbà tí wọ́n wá ibojì òkú rí?