Job 3:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ohun tí mo bẹ̀rù jù ti dé bá mi, ohun tí ń fò mí láyà ti ṣẹlẹ̀ sí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe ohún na ti mo bẹ̀ru gidigidi li o de ba mi yi, ẹ̀ru ohun ti mo bà li o si de si mi yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé ohun náà tí mo bẹ̀rù gidigidi ni ó dé bá mi yìí, àti ohun tí mo fòyà rẹ̀ bá mi ó sì ṣubú lù mí.