Job 3:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí òkùnkùn ṣú bo alẹ́ ọjọ́ náà biribiri, kí á yọ ọ́ kúrò ninu àwọn ọjọ́ tí ó wà ninu ọdún, kí á má sì ṣe kà á kún àwọn ọjọ́ tí wọ́n wà ninu oṣù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki òkunkun ki o ṣúbo oru na biribiri, ki o má ṣe yọ̀ pẹlu ọjọ ọdun na: ki a má ṣe kà a mọ iye ọjọ oṣù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí òkùnkùn kí ó ṣú bo òru náà biribiri, kí ó má ṣe yọ pẹ̀lú ọjọ́ ọdún náà: kí ó má ṣe kà a mọ́ iye ọjọ́ oṣù.