Job 3:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí àwọn tí wọ́n ń fi ọjọ́ gégùn-ún fi gégùn-ún, àní àwọn tí wọ́n lè fi àṣẹ rú Lefiatani sókè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki awọn ti ifi ọjọ gegun ki o fi i gegun, ti nwọn muratan lati rú Lefiatani soke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí àwọn tí í fi ọjọ́ gégùn-ún kí o fi gégùn-ún, tí wọ́n mura tán láti ru Léfíátánì sókè.