Job 30:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí Ọlọrun ti sọ mí di aláìlera, ó sì ti rẹ̀ mí sílẹ̀, wọn dojú ìjà kọ mí ninu ibinu wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti Ọlọrun ti tu okun-ìye mi, o si pọn mi loju; awọn pẹlu si dẹ̀ ijanu niwaju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí Ọlọ́run ti tú okùn ìyè mi, ó sì pọ́n mi lójú; àwọn pẹ̀lú sì dẹ ìjánu níwájú mi.