Job 30:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dínà mọ́ mi, wọ́n dá kún wahala mi, kò sì sí ẹni tí ó lè dá wọn lẹ́kun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn dà ipa-ọ̀na mi rú, nwọn ran jàmba mi lọwọ, awọn ti kò li oluranlọwọ;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n da ipa ọ̀nà mi rú; wọ́n sì sọ ìparun mi di púpọ̀, àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́.