Job 30:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí ni anfaani agbára wọn fún mi, àwọn tí wọn kò lókun ninu?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu agbara ọwọ wọn kini o le igbè fun mi, awọn ẹniti kikún ọjọ wọn kò si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ni ìwúlò agbára ọwọ́ wọn sími, níwọ̀n ìgbà tí agbára wọn ti fi wọ́n sílẹ̀?