Job 30:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣebí mo ti sọkún nítorí àwọn tí wọ́n wà ninu ìṣòro rí, tí mo sì káàánú àwọn aláìní.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kò ha sọkun bi fun ẹniti o wà ninu iṣẹ, ọkàn mi kò ha bajẹ fun talaka bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kò ha sunkún bí fún ẹni tí ó wà nínú ìṣòro? Ọkàn mi kò ha bàjẹ́ fún talákà bí?