Job 30:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo fa ojú ro, mò ń káàkiri, mo dìde nàró láti bèèrè ìrànlọ́wọ́ láàrin àwùjọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi nṣọ̀fọ lọ rinkiri laisi õrùn, emi dide duro ni awujọ, mo si kigbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmí ń rìn kiri nínú ọ̀fọ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe nínú òòrùn; èmi dìde dúró ní àwùjọ mo sì kígbé fún ìrànlọ́wọ́.