Job 30:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ewé igi inú igbó ni wọ́n ń já jẹ, àní, àwọn igi ọwọ̀ tí kò ládùn kankan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ẹniti njá ewe-iyọ li ẹ̀ba igbẹ, gbongbo igikigi li ohun jijẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹni tí ń já ewé iyọ̀ ní ẹ̀bá ìgbẹ́; gbogbo igikígi ni ounjẹ jíjẹ wọn.