Job 30:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nisinsinyii mo ti di orin lẹ́nu wọn, mo ti di àmúpòwe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nisisiyi emi di ẹni-orin fun wọn, ani emi di ẹni-asọrọsi fun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ǹjẹ́ nísinsin yìí, àwọn ọmọ wọn ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà nínú orin; àní èmi di ẹni ìsọ̀rọ̀ sí láàrin wọn.