Job 31:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
jẹ́ kí iyawo mi máa se oúnjẹ fún ẹlòmíràn, kí ẹlòmíràn sì máa bá a lòpọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ ki aya mi ki o lọ ọlọ fun ẹlomiran, ki awọn ẹlomiran ki o tẹ̀ ara wọn li ara rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n kí àyà mi kí ó lọ ọlọ fún ẹlòmíràn, kí àwọn ẹlòmíràn kí ó tẹ̀ ara wọn ní ara rẹ̀.