Job 31:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Bí mo bá kọ̀ láti fetí sí ẹjọ́ àwọn iranṣẹkunrin ati iranṣẹbinrin mi, nígbà tí wọ́n bá fẹ̀sùn kàn mí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi mo ba si ṣe aikà ọ̀ran iranṣẹkunrin mi tabi iranṣẹbinrin mi si, nigbati nwọn ba mba mi jà;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Tí mo bá sì se àìka ọ̀ràn ìránṣẹ́kùnrin mi tàbí ìránṣẹ́bìnrin mi sí, nígbà tí wọ́n bá ń bá mi jà;