Job 31:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣebí ẹni tí ó dá mi ninu oyún, òun kan náà ló dá iranṣẹ mi? Òun ló mọ wá kí wọn tó bí wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o dá mi ni inu kọ li o da a? ẹnikanna ki o mọ wa ni inu?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó dá mi ní inú kọ́ ni ó dá a? Ẹnìkan náà kí ó mọ wá ní inú ìyá wa?